BÍ ÌKÍNI ṢE Ń DÍNKÙ NÍ ILẸ̀ YORÙBÁ — ṢÉ A TI N PADANÙ ÌBỌ̀WỌ̀ FÚN ÀGBÀ?
Nínú àṣà Yorùbá, ìkíni àti ìbọ̀wọ̀ fún àgbà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ohun tó ṣe pàtàkì jù lọ tí a fi ń dá ọmọ rere mọ̀. Láyé àtijọ́, ọmọ Yorùbá máa ń kí àgbà nígbà tó bá rí i, ó sì...